Size / / /

wọ́n ní ilé làá wò ká tóo s’m lórúkọ—

inú ilé tí ati bí'm. àmó ilé tí n ò bá wò

 

ni ó kún fún egbìrìn ̀t̀ yìí—

ilé olórogún—ilé ogun. èmi–jù–ó–

 

ìw–ò–jù–mí, ti s ilé lá di ahoro.

ilé tí ò bu àpónlé fún ni—ilé tí oriki rẹ̀ ò ṣé mú yangàn.

 

àwn ará iwájú ò rò ẹ̀yìn ọ̀la, wọ́n yí orúk mọ̀lẹ́bí mẹ́ẹ̀rẹ̀—

imí létí ọpọ́n ifá - àbùkù rèé lára ohun àpónlé.

 

wọ́n gbàgbé wí pé orúk rere, ó dára ju wúrà òun fàdákà l.

oníyangí ará iwájú tapo sí ààlà  

 

àwn èrò tó n b léyìn. orúk àpọ́nlé

wá dà ohun a ń áá fún bíi aṣọ ẹlẹ́gbin. 

 

bí aṣọ ̀sín. nítorípé okùn mọ̀lẹ́í ti já.

nítorípé ilé tí a bá fi it́ mọ 

 

ìrì ni yóò wo. ilé olórogún, ilé ogun.

orogún ń loogun ogun, ọbàkan ń gbómi ìjà k’aná

 

ilé e b́̀ ó di ajere — janjaanjan bíi iná ọtíkà.

s fún mi—pẹ̀lú àwọn àkàwé yìí—orúkọ wo ni kín s'm?

 

orúkọ rere wo ni n ba s'm

nígbàtí orísun rẹ̀ bá kún fún kìkì ẹ̀jẹ̀?Waheed S. Olamilekan is a writer, thespian and producer. He is the director of Ọrọlabi Productions, a brand dedicated towards the promotion of societal values and cultural exchanges, through the creation of documentaries, short films and stage plays. He is a language and culture enthusiast who have participated in various artistic productions. He directed Jogbo Tuntun, a staged performance in 2022 at the Wole Soyinka Theatre, University of Ibadan. A broadcast journalist with over five years of experience—worked at the Suncity 101.9fm, Ondo State and Diamond 101.1fm, Ibadan.